Presentation is loading. Please wait.

Presentation is loading. Please wait.

GBOLOHUN GBOLOHUN ALAKANPO.

Similar presentations


Presentation on theme: "GBOLOHUN GBOLOHUN ALAKANPO."— Presentation transcript:

1 GBOLOHUN GBOLOHUN ALAKANPO

2 EEKI GBOLOHUN ALAKANPO
Gbolohun alakanpo ni gbolohun meji ti a fi oro – asopo kan po. Bii apeere: Gbol. 1 Mo lo si Oja. Gbol.2 N ko ri ata ra. Akanp0. Mo lo si oja sugbon n ko ri ata ra. Gbol.1 Mo ki Ade. Gbol.2 Ade ko dahun. Akanpo. Mo ki Ade amo ko dahun. Awon oro asopo ni a ya soto ninu abajade gbolohun 1&2

3 ABUDA GBOLOHUN ALAKANPO
Gbolohun alakanpo maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Mo lo si oja sugbon n ko ri ata ra. Mo ki Ade amo ko dahun. Akiyesi: awon oro – ise ni a se iyato fun. Oro – asopo gbodo wa ninu ihun re. Boye ati Bola sun. O le lo tabi ko o duro. Akiyesi : awon oro – asopo ni a se iyato fun. Ero inu gbolohun alakanpo maa n ju eyo kan lo. Olu wa nitori mo fi iwe pe e. Odo kun amo ko gbe eniyan lo. Akiyesi : awon oro ti a se iyato fun duro fun ero kan.

4 APEERE ORO ASOPO TI A LO FI SO GBOLOHUN MEJI TABI JU BEE LO PO.
Si ati sugbon amo Boya tabi/abi ki n to yala---tabi Anbelentase antonbosi bee ni /bee si. ISE SISE : Lo marun-un ninu awon oro – asopo wonyi lati seda gbolohun alakanpo.


Download ppt "GBOLOHUN GBOLOHUN ALAKANPO."

Similar presentations


Ads by Google